EEYAN MẸFA LA PA LẸYIN TA A GBA OWO ITUSILẸ TAN, AAYE LA JU MEJI LARA WỌN SINU KANGA

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 15 сен 2024

Комментарии • 87

  • @FizlandCome
    @FizlandCome Месяц назад

    It's well that's is life

  • @YekiniHamzat
    @YekiniHamzat Месяц назад

    Of nigbogbo file yin mase

  • @AMINURAHMAT
    @AMINURAHMAT Месяц назад

    Olori buruku. O ye ki won dana sun e ni.

  • @febisolakayode3987
    @febisolakayode3987 Месяц назад +3

    Olori buruku,ika eniyan,iwo le maa pa eni ti e kole da,sugbon oo fe ku. Oni ki won dari jie, se iwo dari ji awon too pa lai se? Gbogbo aromodomo yin lo maa ku iku oro loruko JESU 💔 🙏🙏🙏.

  • @maryifeoluwa6902
    @maryifeoluwa6902 Месяц назад +3

    😮,ika ni e o, olorun o ni dari jie

  • @haynehifanny8006
    @haynehifanny8006 Месяц назад +1

    Wón ma pa ẹ ni. Oloriburuku ọmọ alè. Ọmọ atoko-waba'lejẹ.

  • @user-xc4nr7wj7w
    @user-xc4nr7wj7w Месяц назад +5

    Ejo emaran won lewon oo epaa GboGbo wondanu eo nikuree

  • @tonyodey9115
    @tonyodey9115 Месяц назад +6

    They only feel sorry when they get court...this people are so wicked and brutal while operating.

  • @ATINUKERacheal-m4v
    @ATINUKERacheal-m4v Месяц назад

    Else oni lo laiji ya

  • @oluwaseunfelicia2458
    @oluwaseunfelicia2458 Месяц назад +1

    Hmmmmmm o ga oooo, YORUBA e je ka sora oo,hmmmmm awon eyan wonyi,o ni ero rere si wa rara o,e ye gba won sile mooo

  • @Dr.Oduwole
    @Dr.Oduwole Месяц назад +6

    Iku gbona ni Eledumare ma Fi pa gbogbo won

  • @murhioloruntola9935
    @murhioloruntola9935 Месяц назад +12

    When I say Ibos are bigger threat to the Yoruba race than the Fulanis, some Oloriburiku omo ale Yoruba will disagree bcos of religious faith.

    • @AceAce-io5nf
      @AceAce-io5nf Месяц назад

      Ur reasoning is shallow

    • @murhioloruntola9935
      @murhioloruntola9935 Месяц назад

      @@AceAce-io5nf Truth is bitter though

    • @akinwoleabiodun1940
      @akinwoleabiodun1940 Месяц назад

      ​@@murhioloruntola9935like he said your reasoning is so shallow
      So you haven't seen or heard bout a Yoruba kidnapper that was apprehend bfr?

    • @bola6196
      @bola6196 Месяц назад +1

      I am Yoruba, but please stop this stereotyping people, people commit crimes irrespective of tribes or race. There are bad people everywhere.

  • @morayoadedayo9583
    @morayoadedayo9583 Месяц назад +3

    Oloriburuku omo at'oko wa ba ile je

  • @OrigbemisoyeOluwaJenyo
    @OrigbemisoyeOluwaJenyo Месяц назад +3

    Oloriburuku ni awon ibo won yii .be ano ni won se ma se ilu oynibo awon oloriburuku Omo yii ti ba oruko awon Omo nageria ton

  • @SegunLusira-ej5qh
    @SegunLusira-ej5qh Месяц назад +2

    Ejowo oye kiwon so won ma motor ni ki wo won

  • @joyceadenekan5672
    @joyceadenekan5672 Месяц назад +3

    Ki won pa won ni, ki won si pa awon omo won ati iyawo ti won fi owo na nbo.

  • @giwamoshood
    @giwamoshood Месяц назад +2

    Awon omo igbo yii oloroburu ni won ooo😢

  • @oe6526
    @oe6526 Месяц назад +8

    Can nigerians in the diaspora truly say that there is no place like home?
    Ajo 🛫 ko dabi ile 🏠
    Eyin ara America, London, Canada etc. Won ni ki e mo bo nle, ki a jo se.

    • @kemoblunsky3794
      @kemoblunsky3794 Месяц назад +1

      😅😅😅, which home?...Home to ti di rederede

  • @braitkhamadetokun8578
    @braitkhamadetokun8578 Месяц назад +5

    Imagine omo ibo kidnapping us on our soil

  • @user-ns7ot7cw9c
    @user-ns7ot7cw9c Месяц назад

    Lori iro

  • @KassoumMouhamedi
    @KassoumMouhamedi 27 дней назад

    Oloriburukuorowoloatole

  • @mohammedhighbright8356
    @mohammedhighbright8356 Месяц назад +3

    Kosi bi a se le bori awon isele buruku yin ju ki a Pada sibi ofin eleda wa.....
    A pa ofin olohun Oba ti, a ntele ofi awa ara wa.....
    Quran je ko yewa pe: EMI fun EMI ni.... Eni to pa eniyan pipa lere ese re......

  • @user-xu9vw8nh9y
    @user-xu9vw8nh9y Месяц назад +4

    Ko need kié sese ma sewadi inkankan nipa awon eleyi oyeki e pawon danu lekan a ni

  • @delel4161
    @delel4161 Месяц назад +1

    Awon eleribu iran kiran, gbo gbo yin lama she shege metala fun, eje ki tinubu restructure na . ama fojuyin ri mabo

  • @timothywale8055
    @timothywale8055 Месяц назад +1

    Eyin Esu beleke enia wonyii , ekan nda enia laamu kiri igboro, e o le gba ile ibo yin lo , ki Eloo ma pa awon family yin nile ibo lohun , talo ma idariji e ? I won enia ibi, Olorun gan koni dariji e, debi wipe enia ma dariji e

  • @genesisadesope7147
    @genesisadesope7147 Месяц назад

    Eni to ba paayan, iku lo to siruu eni be e! E pa eeyan mefa nipakupa o wa n wa idariji! Olorun nikan lo le dari ji o o kiiseniyan

  • @oriyomiokunoye7772
    @oriyomiokunoye7772 Месяц назад +1

    Huuum awon eleyi da ju ooo

  • @adeyemoademolajammy2002
    @adeyemoademolajammy2002 Месяц назад +1

    Iku lere ese awon eleyi ni kia kia.

  • @olabisiayodele3322
    @olabisiayodele3322 Месяц назад

    Oloriburuku I Ifayi add ti gogo yi ofo le ma se aye yi Ko ni da

  • @gbolahanmartins3598
    @gbolahanmartins3598 Месяц назад

    Efun ni ibon. Ejo eyin olopa. Akalolo omo ale

  • @foyekealawode4963
    @foyekealawode4963 Месяц назад +1

    Eniyan mefa ko ni won pa, Eniyan ti won ti ma pa ati to 500 people

  • @motunrayoajayi6328
    @motunrayoajayi6328 Месяц назад +1

    E pa won danu😢 tiran tiran

  • @BraidClave
    @BraidClave Месяц назад +1

    Oma ku nii . Onijere

  • @akindelemodinat7464
    @akindelemodinat7464 24 дня назад

    They have not seen the leader yet.

  • @user-id5ov8tq3i
    @user-id5ov8tq3i Месяц назад +1

    eyin ibo Dani comment section oloribu Omo iyayin kanreo enijere ni agbara olorun iku Oro lomapayin Tiran Tiran tomotomo lema sanku

  • @adekunleadedapo8573
    @adekunleadedapo8573 Месяц назад

    SE yoruba Le lo si ile ibo la ti SE unkan wonyi. Ibo ni ika gan

  • @KassoumMouhamedi
    @KassoumMouhamedi 27 дней назад

    Egboorolenuwerekiosobabaisalewon

  • @florenceafelumo192
    @florenceafelumo192 Месяц назад +1

    This na una Fulani herdsmen o!

  • @anointed5841
    @anointed5841 Месяц назад +12

    Oloriburuku, ko ni intention ati paayan o nyinbon pa won. Eyin omo Ibo to npe awa Yoruba ni ajinigbe. Se Yoruba tun ni eleyi?

    • @danielthompson2152
      @danielthompson2152 Месяц назад

      People like you are the problem, I’m a Yoruba man , did they push him ? Now I see why you vote this stupid president

  • @motunrayoajayi6328
    @motunrayoajayi6328 Месяц назад

    Oh ma ku nani

  • @ayoayinde8166
    @ayoayinde8166 Месяц назад

    Ti Iran Yoruba o ba ko arawon ni ijanu pelu bi a see nko ajoji mo ara; awon ijamba bayi lao maa rii. Yoruba ni mi ti mo ti n gbe ni ariwa ori 'lede you fun ojo ti o pee; iru eleyi ko sele rii bee nii ko le sele laye ati laye...laye in ile awon Hausa.
    Ani lati so ara gidi gidi!

  • @leko762
    @leko762 Месяц назад

    What is Amotekun doing???

  • @ijemukeomoijemuke3162
    @ijemukeomoijemuke3162 Месяц назад

    This boy is most wicked and heartless ❤ person from eboyin

  • @SaniAtiku-lg8hx
    @SaniAtiku-lg8hx Месяц назад

    Ki won be ori won leyokokan.. . Koni da fun iyalaya to bi iyalaya re... Kosi idajo kankan leyin ki won be ori olosi yi

  • @AdebukolaSam
    @AdebukolaSam Месяц назад

    Oloriburuku ni eee,Idajo to yen ki won se fun e ni ki won Sa e EPA into pieces

  • @jumokerita3102
    @jumokerita3102 Месяц назад

    U can kill another person but U can't kill urself... wicked soul

  • @agbekeaiyedun7107
    @agbekeaiyedun7107 Месяц назад

    😭😭😭😭😭😭😭

  • @oyewole5530
    @oyewole5530 Месяц назад

    Omo ale everything na ifeayin murderer killing their victim anyhow

  • @MonsurudeenOniwa-io7ge
    @MonsurudeenOniwa-io7ge Месяц назад

    Irolonpa walai ogbeniyi ogbologbonioo aaaaaa emajekosewon oo eeee padanu nio

  • @agbaman123
    @agbaman123 Месяц назад

    This had nothing to do with tribe. Ika was ninu yoruba, ibo ATI Hausa. Ika ni ika n je. Ko si eya ti ko ni awon eyan buruku

  • @mariamasie9329
    @mariamasie9329 Месяц назад

    Ara awon to nba Orilede Nigeria je niyi, awon naa ni won ma sise fun Oloselu ati awon thugs to gbogun ti iwode worowo, Aye gbogbo yin ma baje ni.

  • @sakiruowolabi5370
    @sakiruowolabi5370 Месяц назад

    Pipa ni kie paa gbogbo won pata pata nio

  • @RazeedAyinki
    @RazeedAyinki Месяц назад

    Oloriburuku omo wahala niyin epa won danu

  • @rotimiilesanmi1171
    @rotimiilesanmi1171 Месяц назад

    They are the first to call Nigeria zoo. Now we can see them as the real animals that are living in the zoo. They blame everything on Fulani as if they too are innocents. Shame on you. See the criminal talking like a repentant prodigal son after he is caught. He did not kill himself after 1st, 2nd, 3rd .... killings, but now.

  • @adesewa100
    @adesewa100 Месяц назад +1

    You're saying this trash because police arrested you ... nonsense

  • @nikkiroe7528
    @nikkiroe7528 Месяц назад

    Who’s Ifeayean 😫😫😫

  • @LawalOshoma
    @LawalOshoma Месяц назад

    This is how Igbo and fulani killing Yoruba
    Yet some idiots are saying only Fulani

  • @KehindeoseniSaliman-ou4jt
    @KehindeoseniSaliman-ou4jt Месяц назад

    Oloriburuku ni awon ibo ki won TE TE SE ofin ooo Eni ajogi tio ba ti pa OMO Yoruba ni Ori Ile WA ki won Le gbogbo ajogi Yen kuro ni gbogbo Ile Yoruba patapata ni ooo

  • @Fattylincorn
    @Fattylincorn Месяц назад

    And yibo are the loudest in Nigeria. BUNCH of kriminals

  • @oyewole5530
    @oyewole5530 Месяц назад

    Begging for forgiveness after wasting so many lives

  • @KehindeoseniSaliman-ou4jt
    @KehindeoseniSaliman-ou4jt Месяц назад

    idi ti AFI ni wipe ki awa Yoruba kuro ni inu one Nigeria radarada Yi re ooo ni tori awon oloriburuku OMO ibo ATI Fulani Hausa Yi awon ajogi Yi NDA awa iran Yoruba LAmun pipoju ni Ori Ile WA ooo

    • @lifezoe2899
      @lifezoe2899 Месяц назад

      I laugh when people comment like this. What we yorubas do to ourselves is more deadly..

    • @adecrown4413
      @adecrown4413 Месяц назад

      Sebi ore Ibo niyin. Ibo nio pa gbogbo yin tan. E kare Yoruba toto. Ekare.

  • @joyceadenekan5672
    @joyceadenekan5672 Месяц назад

    Gbogbo Igbo ni ljebu lgbo pata ni ki won bere si ni le karo ni gbogbo Ogun State. Look at them travelling from Anambra to abduct people in another State.

  • @toyinalli-rl8dk
    @toyinalli-rl8dk Месяц назад

    Evil and wicked people